Matthew 27:32

A kan Jesu mọ́ àgbélébùú

32 aBí wọ́n sì ti ń jáde, wọ́n rí ọkùnrin kan ará Kirene tí à ń pè ní Simoni. Wọ́n sì mú ọkùnrin náà ní túláàsì láti ru àgbélébùú Jesu.
Copyright information for YorBMYO